languagesoftware.net - which is the best language course or software - compare

Useful phrases in Yorùbá

A collection of useful phrases in Yorùbá. Click on the English phrases to see them in many other languages.

English Yorùbá
Welcome Ẹ ku abọ
Hello
(General greeting)
Ẹ n lẹ
How are you?
I'm fine, thanks. And you?
̣Se daadaa ni o wa?
Mo wa daadaa, o ̣se. Iwọ naa n kọ?
Long time no see O to ọjọ mẹta o / O pẹ ti a ri ara wa o
What's your name?
My name is ...
Ki ni orukọ rẹ?
Orukọ mi ni……
Where are you from?
I'm from ...
Nibo ni o ti wa?
Mo wa lati ...
Pleased to meet you Inu mi dun lati mọ ọ
Morning greeting(s) Ẹ ku aarọ
Afternoon greeting(s) Ẹ ku ọsan
Evening greeting(s) Ẹ ku alẹ
Nighttime parting phrase(s) O da aarọ
Parting phrase(s) O da abọ
Good luck Yoo dara o / Yoo bọ si o
Toasts used when drinking Ayọ ni o / Kara o le
Have a nice day Oni a dara o
Bon appetit /
Have a nice meal
Ounjẹ ajẹye o / Yoo gba ibi re
Bon voyage /
Have a good journey
O da abọ / Ka sọ layọ o
I don't understand Ko ye emi
Please speak more slowly Jọwọ, rọra maa sọrọ
Please say that again Jọwọ, tun un sọ
Please write it down Jọwọ, kọ ọ silẹ
Do you speak Yorùbá?
Yes, a little
̣Se o n sọ Yorùbá?
Bẹẹ ni, diẹ
How do you say ... in Yorùbá? Bawo ni o se le sọ ….. ni Yorùbá
Excuse me Ẹ ̣se fun mi / Ẹ jọwọ, ẹ gbọ mi
How much is this? Eelo ni eyi?
Sorry Pẹlẹ
Thank you
Response
O ̣se / E se
Ko to ọpẹ
Where's the toilet? Nibo ni ile igbọnsẹ wa?
This gentleman/lady will pay for everything Alagba/Iyaafin yii yoo sanwo fun gbogbo rẹ
Would you like to dance with me? ̣Se iwọ maa ba mi jo?
I love you Mo nifẹẹ rẹ
Get well soon Da ara ya o
Leave me alone! Fi mi silẹ
Help!
Fire!
Stop!
Ẹ gba mi o!
Ina o!
Duro nbẹ!
Call the police! Pe awọn ọlọpaa
Christmas and New Year greetings Ẹ ku Ayọ Keresimesi ati Ọdun Tuntun
Easter greetings Ẹ ku Ayọ Ajinde
Birthday greetings Ẹ ku Ayọ Ọjọ Ibi
One language
is never enough
Ede kan ko to ri rara
My hovercraft
is full of eels
Ọkọ afategun-sare mi kun fun ẹja arọ

Yorùbá phrases provided by Adedamola Olofa

If you would like to make any corrections or additions to this page, or if you can provide recordings, please contact me.

Information about Yoruba | Useful phrases in Yoruba | Tower of Babel in Yoruba | Yoruba learning materials

Links

Other collections of Yorùbá phrases
http://www.motherlandnigeria.com/languages.html
http://www.abeokuta.org/yoruba.htm

Phrases in Niger-Congo languages

Ewe, Igbo, Kinyarwanda, Lozi, Ndebele (Northern), Sesotho, Shona, Swahili, Tswana, Tumbuka, Umbundu, Wolof, Xhosa, Yorùbá, Zulu

Phrases in other languages


Learn Chinese Characters with the Omniglot Chinese app | Language Jobs at Jobseeker.co.uk
Special offer on SaySomethingInSpanish | Learn Languages faster | Hosted by Kualo